• Alága Àgbà Fún Àwon Akékòó OSPOLY, Òmòwé Tópé Abiola, Ro Àwon Ólùdíje Saaju Eetò Ìdìbò Lati Sàmulo Oju Opo Ayélujára

     


    Omololú Àjàyí

    Oga àgbà lęka igbayegbadun àwon akékòó nileękó gbogbonise ilu iree nipinle Osun, Omowe Tope Abiola ti kesi àwon akékòó toun jíde fun ipo òsèlú lati samulo èrö ayélujára fun ipolongo ìbò eleyi ti yio waye ni kòpékòpé yii.


    Oloye Olutope lo fi òròyi lede loni, ni gbòngàn ìkékòö  àkókó ti awòn akékòó nipa isé iroyin ati igbohunsafefe (NLH1).


    Òmòwe Olutope wa fi kun òrò rè wipe eyikeyi olùdije to ba n dije dupo oselu kan yala ni ìgbongun eleyii togajulo (SUG) tabi eleyi to powole ko sora lati mo ba dúkia ileèkoo je.


    O wa ténumó òrò naa o si tun se lálàyé wipe ki àwon adari o kilo fun àwon omoléyìn lati mo le aworan ipolongo ibo sara eyikeyi pátákó ileeko, ki won o mo sì fi òdà kun opopona ijoba pelu, ki won o lo oju opo ayélujára fun eyikeyi ipolongo ibo naa.


    Ómòwe Olutope wa ro àwon akęköö ti won ko tii pada sile èkó fun ti saa yii, paapaajulo àwon akékòó towa labala togbeyin lati pada sileeko léyeośöka ki won o mo baa padanu oun toyę.

    Gbogbo ẹtọ wa ni ipamọ. O ko ni ẹtọ lati tun tabi ṣe atẹjade eyikeyi akoonu lati oju opo wẹẹbu yii laisi igbanilaaye kikọ lati ọdọ NEB. 

    Kan si Olootu;@NAMACOSONLINE

    No comments