Ìdìbò OSPOLY: Ó Mà Se oo PATH Dojúbolè Láì Fesè Ko
Oseni laanu gbaa ni bi ajo to n ri si eto idibo ti ile iwe gbogbonise ti ipinle osun to fidikale si ilu iree se yo oruko Path ati awon miiran bi eni yo jiga ni bi ajo na se se afihan oruko Awon ti o kun oju osuwon lati dije fun ipo isejoba egbe akeeko ile iwe na
Eyi lo foju hande ninu akojo ti alaga eleto idibo ile iwe na buwo lu ti o si je wipe oludije metala pere lo danto lati dije
Oruko Awon to danto oun ni
AZEEZ TAJUDEEN ADEBAYO (Honourable)- Aree Oluyeye Kayode Alade (PKAY)- Akowe agba ; Adebayo Afees (physo)-Akowe owo ; OYENIYI SHERIFFDEEN AYOMIDE ( BRIGHT)- igbakeji Akowe; ATEWOGBADE SODIO AYODEJI (God’s Time)-igbakeji Akowe; AKOGUN JOSHUA TEMITOPE (MOJ)- alabojuto ; OGUNGBEMI FLORENCE (Lizzy Aluta)- Treasurer ; OLADOKUN DOYINSOLA PRECIOUS (Express) -Social director ; OSHOKOYA AZEEZ OLANRE WAJU- (DJ EAZI) - Social Director ; ADELEKE KEHINDE (Dave Spenzer)- asayewo iwe owo ; KOLAWOLE OLAPOSI ( Boro)- oludari ere idaraya ; OLAJIDE OLARINDE(NOKIA)- oludari ere idaraya; DARAMOLA PELUMI STEPHEN( Dass) - Alukoro
Ninu iforojomitoro oro pelu alaga oun lo ti safihan ohun ti o re path ni igi eyin lati dije wipe esi idanwo re ko kun to oju osuwon. Ese ranti wipe Awon alakoso ile iwe yi ni o ti fi lede wipe oludije si ipo aree egbe akeeko gbodo ni 2.70 gege bi esi idanwo re ti ko si gbodo ni ijakule bi o ti wu ko kere mo
Gbogbo ẹtọ wa ni ipamọ. O ko ni ẹtọ lati tun tabi ṣe atẹjade eyikeyi akoonu lati oju opo wẹẹbu yii laisi igbanilaaye kikọ lati ọdọ NEB.

No comments